Ádúrà Egberun-Odin-Laadota Ti O Bori Emi Adaniduro Ati Afi Ibukun Eni Si Abamo

ebook

By Dr. Olusola Coker

cover image of Ádúrà Egberun-Odin-Laadota Ti O Bori Emi Adaniduro Ati Afi Ibukun Eni Si Abamo

Sign up to save your library

With an OverDrive account, you can save your favorite libraries for at-a-glance information about availability. Find out more about OverDrive accounts.

   Not today

Search for a digital library with this title

Title found at these libraries:

Loading...
Ẹ̀mi ágbé áwọ́n ibùkún ẹ́ni dè á máá dì nì lọ́wọ́ àtí wọ́nú àyànmọ̀ lọ́ lásìkò, lòdì sí ákitiyán àtí ìlépá.Áwọ́n írúfẹ́ énià bẹ́ẹ́ tí wọ́n ńjìyà lábẹ́ irú ẹ̀mi báyì á máa lò ọ́pọ́lọ́pọ́ ákókó kí wọ́n tó lé rí áwọ́n óhún tí ẹ́lẹ́gbẹ́ wọ́n mìràn ńri gbà láişé wáhálà jínà. Wọ́n á máá şéşẹ́ àşékú kí wọ́n lé rí óhún kán. Nìgbà ti wọ́n bá sì má rí óhún nàà gbà tàn, gbógbó àyọ́ tió só mọ́ yió tí kọ́ fò lọ́ ná sájú. Bibélì sọ́ pé, "iréti pipẹ́ á máá mú ọ́kàn şẹ́ áárẹ̀" Nígbàtí ó bá şé àkíyèsí ọ́kùnrin tàbì óbirín tí ẹ́mi yiì ńdà láàmú, gbógbó áwọ́n tió kéré sí wọ́n á máá rí ńkàn gbà kiákiá şájú wọ́n. Nígbà tí áwọ́n irú éniyàn báwọ́nyì bá sá ipá tí wọ́n, ọ́nà á há mọ́ wọ́n, à lé kókó. Wọ́n á máá sán óyé tí ó pọ́ jáì làtí rí oúnkòhún gbà, wọ́n máa ń sábá jẹ́ ẹ́níkẹ́hìn làtí rí ìbùkún gbà, ẹ́nikẹ́yìn làtí rí admissionù sí kọ́lẹ́jì, làtí şé àşéyọ́rí ńnú ídànwò, làtí gbéyàwó tàbì l'ọ́kọ́, làtí l'ọ́mọ́ pààpàà. Wọ́n á tùn máa gbẹ̀yìn pààpàà làtí làlùyọ́. Órúkọ́ àrín tí wọ́n ńjẹ́ à fẹ́ẹ́ lé yì pádà sí bùrọ̀dà tábì auntì ákẹ́yìn tábì ìgbẹ̀yin. Ìbùkún wọ́n kìì sábá dé bọ́rọ̀. Ítan Jákọ̀bù fí áwòràn írú éyí hàn wà, òhún tí ẹ̀mi ádábùkún ẹ́ni dúró lé şé sí áyié ẹ́ní níyì. Bió tílẹ̀ şé pé áwọ́n ìbùkún Jehofa mbẹ́ lóri rẹ̀, ó jiyà ìnírá ti kò şé f'ẹ́nú sọ́ lọ́wọ́ Lábáni. Bi ò tí ńgbàdúrà lóni, Ólúwá yiò fọ́ àjàgà ẹ́mi yì kúrò nínú áyié rẹ̀, iwọ́ yiò wà wọ́nú àyànmọ̀ rẹ́ lọ́ ni orúkọ́ Jésù.Ní wíwò ẹ̀mì ádánidúró àtí àgbé àwọ́n ìbùkún ẹ́ni dè yì síwájú síí Bíbórí ẹ̀mi ìdádúró àtí ágbé-bùkún dè yì jẹ́ àigbọ́dọ́ mójúkúrò lará rẹ̀ fún ọ́ nitóripé áwọ́n éniyàn wà ti á bí látí jẹ́ Òlùdárí, Álágá ilé-şẹ́ ọ́pọ́-ilú súgbọ́n tí wọ́n nsé Áşọ́bódè lásán nipásẹ̀ ípá ẹ́mi yì. Áwọ́n éniyàn mìràn yẹ́ kí wọ́n jẹ́ Álábójútó gbógbó-gbó súgbọ́n wọ́n jẹ́ òlùdárí àwọ́n ilé isìn kéréjé-kéréjé ninú igbérikó lọ́wọ́ báyì.Áwọ́n ẹ̀lómiràn ní àyànmọ̀ àtí jẹ́ professor sùgbọ́n wọ́n ńsé òlùkọ́ ilé-wé lásán báyì nitóripé ẹ́mi ìdádúró àtí ágbébùkún dè yi wà lójú işẹ́ nínú áyié wọ́n. Áwọ́n miràn tìlẹ̀ yẹ́ ki wọ́n jẹ́ Billionaire, multi–millionaire súgbọ́n wọ́n ńtọ́rọ́ jẹ́ lọ́wọ́ báyì. ọ́pọ́lọ́pọ́ éniyàn ní wọ́n tí dí àgbésín pẹ́lù talentì Ọlọ́rún lárá wọ́n, wọ́n mbẹ́ ninú íbójì áwọ́n òkú báyì.ọ́pọ́ éniyàn ní ó wà nínú sáàrè ti wọ́n kú pẹ́lù áwọ́n álá àtí ìràn ti wọ́n kò rì múşẹ́ nitóri ẹ́mi ìdádúró àtí ágbébùkún dè yì. Áwọ́n iwé ti ó lé yí ìgbé áyié ẹ́dá pádà sí àrà ńlá mbẹ́ ní íbójì áwọ́n òkú, áwọ́n irú éyi tí ẹ́nikẹ́ni kòi tì kọ́ rí, nipásẹ̀ ẹ̀mi ìdádúró àtí ágbébùkún áyié ẹ́ni dè yì, ó tí şí wọ́n lọ́wọ́ báyì.Ákò lé sé àìrí áwọ́n miràn tí wọ́n ní àyànmọ́ àtí túnşé, wọ́n lé yí órilẹ̀-édé pádà sí gígá súgbọ́n wọ́n mbẹ́ ninú sáàrè t'áwọ́n tí álá wọ́nyi, wọ́n kò ní lé múşẹ́ mọ́ láilái.Iwọ́ tí ò ńkà iwé yì lọ́wọ́ báyì, tá ló mọ̀ bóyá ibi ti ó wà báyì kíì şé ibi ti óyẹ̀ fún ọ́? Ó níilò àtí gbà gbógbó áwọ́n kókó ẹ́gbẹ́rùn-dínláádọ́ta ádùrà inú iwé yì.
PUBLISHER: TEKTIME
Ádúrà Egberun-Odin-Laadota Ti O Bori Emi Adaniduro Ati Afi Ibukun Eni Si Abamo