Ìkẹtàlá Ti Megan

ebook Atọ́nà Ẹ̀mí Kan, Ànjọ̀nnú Ẹkùn Kan Àti Ìyá Kan Tí Ó Kọni Lóminú

By Owen Jones

cover image of Ìkẹtàlá Ti Megan

Sign up to save your library

With an OverDrive account, you can save your favorite libraries for at-a-glance information about availability. Find out more about OverDrive accounts.

   Not today

Search for a digital library with this title

Title found at these libraries:

Loading...

Ìkẹtàlá Ti Megan ni ọ̀wọ́ kejì nínú mẹ́tàlélógún ti Ipele Megan. Ó jẹ́ ọjọ́ ìbí Megan tí ó ní agbára nínú ẹ̀mí. Láti ṣe àjọyọ̀ rẹ̀ pé ó da ọ[dọ́, àwọn òbí rẹ̀ nṣe àpèjẹ nlá kan fún u. Tẹbí tọ̀rẹ́ ni wọ́n pè síbi ayẹyẹ nlá náà, níbi tí olùṣètò orin tí ó jẹ́ akọni rẹ̀, Jack Hammer yóò ti gbé àwọn orin jáde. Ó ndà á rò bóyá ẹnikẹ́ni fi ojú sọ Grrr, àléjò rẹ̀ nlá tíí ṣe ànjọ̀nnú Ẹkùn ará ilẹ̀ Siberia. Kò máa níi ́lọ́kàn láti pàdé àlejò kan tí ó rẹwà lọ́kùnrin. Ipele Ti Megan wà fún àwọn ènìyàn láìfi ti ọjọ́ orí ṣe tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí ọ̀rọ̀ ti ẹ̀mí.

Ìkẹtàlá Ti Megan